Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Offerings: First-fruits

2 ẹsẹ · 61 abala

Àwọn ẹsẹ nípa First-fruits

  1. “Ìwọ kò gbọdọ̀ lọ́ra láti mú ọrẹ wá fún mi láti inú ìre oko rẹ àti láti inú wáìnì rẹ. “Àkọ́bí ọmọ rẹ ọkùnrin ni ìwọ yóò fi fún mi.

  2. Àkọ́so irúgbìn ọkà rẹ, ti wáìnì àti ti òróró rẹ, àti àkọ́rẹ́ irun àgùntàn rẹ ni ìwọ yóò fi fún wọn.