Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Duke

33 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì

Sẹ́ nípa ìwé
  1. Àwọn wọ̀nyí ni orúkọ àwọn baálẹ̀ tí ó ti ọ̀dọ̀ Esau jáde wá, ní orúkọ ìdílé wọn, bí ìpínlẹ̀ wọn ti rí: baálẹ̀ Timna, baálẹ̀ Alfa, baálẹ̀ Jeteti.

  2. Baálẹ̀ Oholibama, baálẹ̀ Ela, baálẹ̀ Pinoni,

  3. baálẹ̀ Kenasi, baálẹ̀ Temani, baálẹ̀ Mibsari,

  4. Magdieli, àti Iramu. Àwọn wọ̀nyí ni baálẹ̀ Edomu, gẹ́gẹ́ bí wọn ti tẹ̀dó sí ilẹ̀ tí wọ́n gbà. Èyí ni Esau baba àwọn ará Edomu.

  5. Hadadi sì kú pẹ̀lú. Àwọn baálẹ̀ Edomu ni: baálẹ̀ Timna, baálẹ̀ Alfa, baálẹ̀ Jeteti

  6. baálẹ̀ Oholibama, baálẹ̀ Ela, baálẹ̀ Pinoni.

  7. Baálẹ̀ Kenasi, baálẹ̀ Temani, baálẹ̀ Mibsari,

  8. Magdieli àti Iramu. Àwọn wọ̀nyí ni baálẹ̀ Edomu.