Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Answers To Prayer: Sometimes differently from our desire

2 ẹsẹ · 85 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Sometimes differently from our desire

  1. Nítorí nǹkan yìí ni mo ṣe bẹ Olúwa nígbà mẹ́ta pé, kí ó lé e kúrò lára mi.

  2. Òun sì wí fún mi pé, “Oore-ọ̀fẹ́ mi tó fún ọ, nítorí pé a sọ agbára mi di pípé nínú àìlera.” Nítorí náà tayọ̀tayọ̀ ni èmi ó kúkú máa fi ṣògo nínú àìlera mi, kí agbára Kristi lè máa gbé inú mi.