Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Answers To Prayer: Promised especially in times of trouble
Àwọn ẹsẹ nípa Promised especially in times of trouble
Kí o sì pè mí ní ọjọ́ ìpọ́njú, èmi yóò gbà ọ́, ìwọ yóò sì bu ọlá fún mi.”
Òun yóò pè mí, èmi yóò sì dá a lóhùn; èmi yóò wà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ìpọ́njú, èmi yóò gbà á, èmi yóò sì bu ọlá fún un.