Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Answers To Prayer: Abraham

1 ẹsẹ · 85 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Abraham

  1. Ṣùgbọ́n ní ti Iṣmaeli, mo gbọ́ ohun tí ìwọ wí, èmi yóò bùkún fún un nítòótọ́, èmi ó sì mú un bí sí i, yóò sì pọ̀ sí i, òun yóò sì jẹ́ baba fún àwọn ọmọ ọba méjìlá, bẹ́ẹ̀ ni èmi yóò sì sọ ọ́ di orílẹ̀-èdè ńlá.