Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Answers To Prayer: Samuel
Àwọn ẹsẹ nípa Samuel
Nígbà náà ni Samuẹli mú ọ̀dọ́-àgùntàn tí ó jẹ́ ọmọ ọmú, ó sì fi rú ẹbọ sísun sí Olúwa. Ó sí ké pe Olúwa nítorí ilé Israẹli, Olúwa sì dá a lóhùn.