Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Answers To Prayer: Jonah

2 ẹsẹ · 85 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Jonah

  1. Ó sì wí pé: “Nínú ìpọ́njú mi ni mo kígbe sí Olúwa, òun sì gbọ́ ohùn mi. Mo kígbe láti inú ipò òkú, mo pè fún ìrànwọ́, ìwọ sì gbọ́ ohùn mi.

  2. Olúwa sì pàṣẹ fún ẹja náà, ó sì pọ Jona sí orí ilẹ̀ gbígbẹ.