Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Agriculture or Husbandry: Patience in waiting
Àwọn ẹsẹ nípa Patience in waiting
Nítorí náà ará, ẹ mú sùúrù títí di ìpadà wá Olúwa. Kíyèsi i, àgbẹ̀ a máa retí èso iyebíye ti ilẹ̀, a sì mú sùúrù dè é, títí di ìgbà àkọ́rọ̀ àti àrọ̀kúrò òjò.