Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Agriculture or Husbandry: Against the trespass of cattle

1 ẹsẹ · 75 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Against the trespass of cattle

  1. “Bí ọkùnrin kan bá ń bọ́ ẹran ọ̀sìn rẹ̀ lórí pápá tàbí nínú ọgbà àjàrà, tí ó sì jẹ́ kí ó lọ jẹ nínú oko ẹlòmíràn, a ó mú kí ó san ohun ti ẹran rẹ̀ jẹ padà pẹ̀lú èyí tí ó dára jù nínú oko tàbí nínú ọgbà rẹ̀ (ẹlòmíràn padà fún un).