Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Abraham: Sarah, his wife, dies
Àwọn ẹsẹ nípa Sarah, his wife, dies
Sara sì pé ọmọ ọdún mẹ́tàdínláàádóje (127).
Ó sì kú ní Kiriati-Arba (ìyẹn ní Hebroni) ní ilẹ̀ Kenaani, Abrahamu lọ láti ṣọ̀fọ̀ àti láti sọkún nítorí Sara.