Fò sí àkóónú

Zedekiah

52 ẹsẹ · 5 ọmọ ẹbí

A tún mọ̀ ọ́n sí: Mattaniah

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Zedekiah

Sẹ́ nípa ìwé
  1. Ní Ribla ni ọba Babeli ti pa ọmọkùnrin Sedekiah lójú rẹ̀; ó sì tún pa gbogbo àwọn aláṣẹ Juda.

  2. Lẹ́yìn náà, ọba Babeli yọ Sedekiah ní ojú, o sì fi ẹ̀wọ̀n dè é, ó sì gbe e lọ sí Babeli níbi tí ó ti fi sínú ọgbà ẹ̀wọ̀n títí di ọjọ́ ikú rẹ̀.