Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Unbelief: The portion of, awarded to all unfaithful servants
Àwọn ẹsẹ nípa The portion of, awarded to all unfaithful servants
Olúwa ọmọ ọ̀dọ̀ náà yóò dé ní ọjọ́ tí kò retí rẹ̀, àti ní wákàtí tí kò dábàá, yóò sì jẹ ẹ́ ní yà gidigidi, yóò sì yan ipò rẹ̀ pẹ̀lú àwọn aláìgbàgbọ́.