Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Unbelief: The devil taking away the word out of the heart
Àwọn ẹsẹ nípa The devil taking away the word out of the heart
Àwọn ti ẹ̀bá ọ̀nà ni àwọn tí ó gbọ́ nígbà náà ni èṣù wá ó sì mú ọ̀rọ̀ náà kúrò ní ọkàn wọn, kí wọn má ba à gbàgbọ́, kí a sì gbà wọ́n là.