Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Unbelief: Shall not enter rest
Àwọn ẹsẹ nípa Shall not enter rest
Àwa sì rí i pé wọn kò lè wọ inú rẹ̀ nítorí àìgbàgbọ́.
Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí á múra gírí láti wọ inú ìsinmi náà, kí ẹnikẹ́ni má ba à ṣubú nípa irú àìgbàgbọ́ kan náà.