Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Truth: The church is the pillar and ground of truth
Àwọn ẹsẹ nípa The church is the pillar and ground of truth
Ṣùgbọ́n bí mo bá pẹ́, kí ìwọ lè mọ̀ bí ó ti yẹ fún àwọn ènìyàn láti máa hùwà nínú ilé Ọlọ́run, tì í ṣe ìjọ Ọlọ́run alààyè, ọ̀wọ́n àti ìpìlẹ̀ òtítọ́.