Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Truth: Is sanctifying
Àwọn ẹsẹ nípa Is sanctifying
Sọ wọ́n di mímọ́ nínú òtítọ́, òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ rẹ.
Èmi sì ya ara mi sí mímọ́ nítorí wọn, kí a lè sọ àwọn tìkára wọn pẹ̀lú di mímọ́ nínú òtítọ́.