Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Truth: The church is the pillar and ground of
Àwọn ẹsẹ nípa The church is the pillar and ground of
Ṣùgbọ́n bí mo bá pẹ́, kí ìwọ lè mọ̀ bí ó ti yẹ fún àwọn ènìyàn láti máa hùwà nínú ilé Ọlọ́run, tì í ṣe ìjọ Ọlọ́run alààyè, ọ̀wọ́n àti ìpìlẹ̀ òtítọ́.