Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Truth: Are not valiant for

1 ẹsẹ · 73 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Are not valiant for

  1. Wọ́n ti pèsè ahọ́n wọn sílẹ̀ bí ọfà láti fi pa irọ́; kì í ṣe nípa òtítọ́ ni wọ́n fi borí ní ilẹ̀ náà. Wọ́n ń lọ láti inú ẹ̀ṣẹ̀ kan sí òmíràn; wọn kò sì náání mi, ní Olúwa wí.