Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Devil: Satan
Àwọn ẹsẹ nípa Satan
Satani sì dúró ti Israẹli, ó sì ti Dafidi láti ka iye Israẹli.
Ǹjẹ́ ó di ọjọ́ kan, nígbà tí àwọn ọmọ Ọlọ́run wá í pé níwájú Olúwa, Satani sì wá pẹ̀lú wọn.