Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Devil: Ruler of the darkness of this world
Àwọn ẹsẹ nípa Ruler of the darkness of this world
Nítorí pé kì í ṣe ẹ̀jẹ̀ àti ẹran-ara ní àwa ń bá jìjàkadì, ṣùgbọ́n àwọn ìjòyè, àwọn ọlọ́lá, àwọn aláṣẹ ìbí òkùnkùn ayé yìí, àti àwọn ẹ̀mí búburú ní ojú ọ̀run.