Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Devil: Beelzebub
Àwọn ẹsẹ nípa Beelzebub
Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn Farisi gbọ́ èyí, wọ́n wí pé, “Nípa Beelsebulu nìkan, tí í ṣe ọba ẹ̀mí èṣù ni ọkùnrin yìí fi lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.”