Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Issachar: Bounds of their inheritance
Àwọn ẹsẹ nípa Bounds of their inheritance
Kèké kẹrin jáde fún Isakari, agbo ilé ní agbo ilé.
Lára ilẹ̀ wọn ni èyí: Jesreeli, Kesuloti, Ṣunemu,
Hafraimu, Ṣihoni, Anaharati,
Rabiti, Kiṣioni, Ebesi,
Remeti, Eni-Gannimu, Eni-Hada àti Beti-Pasesi.
Ààlà náà sì dé Tabori, Ṣahasuma, àti Beti-Ṣemeṣi, ó sì pin ní Jordani. Wọ́n sì jẹ́ ìlú mẹ́rìndínlógún àti ìletò wọn.
Ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn jẹ́ ìní ẹ̀yà Isakari, ní agbo ilé agbo ilé.