Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Sacred Vail: Was rent at the death of our Lord

3 ẹsẹ · 13 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Was rent at the death of our Lord

  1. Lójúkan náà aṣọ ìkélé tẹmpili fàya, láti òkè dé ìsàlẹ̀. Ilẹ̀ sì mì tìtì. Àwọn àpáta sì sán.

  2. Aṣọ ìkélé tẹmpili sì fàya sí méjì láti òkè dé ìsàlẹ̀.

  3. Òòrùn sì ṣú òòkùn, aṣọ ìkélé ti tẹmpili sì ya ní àárín méjì.