Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Sacred Vail: Could not enter without blood

2 ẹsẹ · 13 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Could not enter without blood

  1. “Báyìí ni Aaroni yóò ṣe máa wá sí Ibi Mímọ́ Jùlọ pẹ̀lú ọ̀dọ́ akọ màlúù fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àti àgbò fún ẹbọ sísun.

  2. Ṣùgbọ́n sínú èkejì ni olórí àlùfáà nìkan máa ń lọ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo lọ́dún, fún ara rẹ̀, àti fún ìṣìnà àwọn ènìyàn.