Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Sacred Vail: (Rending of,) of the death of Christ which opened heaven to saints

3 ẹsẹ · 13 abala

Àwọn ẹsẹ nípa (Rending of,) of the death of Christ which opened heaven to saints

  1. Nítorí Kristi kò wọ ibi mímọ́ tí a fi ọwọ́ ṣe lọ tí i ṣe àpẹẹrẹ ti òtítọ́; ṣùgbọ́n ó lọ sí ọ̀run pàápàá, nísinsin yìí láti farahàn ní iwájú Ọlọ́run fún wa.

  2. Ará, ǹjẹ́ bí a ti ní ìgboyà láti wọ inú Ibi Mímọ́ Jùlọ nípasẹ̀ ẹ̀jẹ̀ Jesu,

  3. nípa ọ̀nà títún àti ààyè, tí o yà sí mímọ́ fún wa, àti láti kọjá aṣọ ìkélé èyí yìí ní, ara rẹ̀;