Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Power of God: Long for exhibitions

2 ẹsẹ · 51 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Long for exhibitions

  1. Saamu ti Dafidi. Nígbà tí ó wà nínú aginjù Juda. Ọlọ́run, ìwọ ni Ọlọ́run mi, nígbà gbogbo ni mo ń ṣàfẹ́rí rẹ, òǹgbẹ rẹ ń gbẹ ọkàn mi, ara mi fà sí ọ, ní ilẹ̀ gbígbẹ àti ilẹ̀ tí ń ṣàárẹ̀ níbi tí kò sí omi.

  2. Èmi ti rí ọ ní ibi mímọ́, mo rí agbára àti ògo rẹ.