Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Power of God: Magnified

2 ẹsẹ · 51 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Magnified

  1. Gbígbéga ni ọ́ Olúwa, nínú agbára rẹ; a ó kọrin, a ó yín agbára a rẹ̀.

  2. tí Ọlọ́run ọlọ́gbọ́n nìkan ṣoṣo, Olùgbàlà wa, ní ògo àti ọláńlá, ìjọba àti agbára, nípasẹ̀ Jesu Kristi Olúwa wa, kí gbogbo ayé tó wà, nísinsin yìí àti títí láéláé! Àmín.