Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Power of God: Delivered by

2 ẹsẹ · 51 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Delivered by

  1. “Àwọn ni ìránṣẹ́ rẹ àti ènìyàn rẹ àwọn tí ìwọ rà padà pẹ̀lú agbára ńlá rẹ àti ọwọ́ agbára ńlá rẹ.

  2. Bí ẹ̀yin bá jù wá sínú iná ìléru, Ọlọ́run tí àwa ń sìn lágbára láti gbà wá kúrò nínú rẹ̀, yóò sì gbà wá lọ́wọ́ ọ̀ rẹ, ìwọ ọba.