Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Power of God: Everlasting

2 ẹsẹ · 51 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Everlasting

  1. Gbẹ́kẹ̀lé Olúwa títí láé, nítorí Olúwa, Olúwa ni àpáta ayérayé náà.

  2. Nítorí pé láti ìgbà dídá ayé, gbogbo ohun àìlèfojúrí rẹ̀, bí agbára ayérayé àti ìwà-bí-Ọlọ́run rẹ̀ ni a rí gbangba tí a sì ń fi òye ohun tí a dá mọ̀ ọ́n kí ènìyàn má ba à wá àwáwí.