Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Power of God: Establishing and governing all things
Àwọn ẹsẹ nípa Establishing and governing all things
ìwọ tí ó dá òkè nípa agbára rẹ, tí odi ara rẹ ní àmùrè agbára,
Ó ń jẹ ọba títí láé nípa agbára rẹ̀, ojú rẹ̀ ń wo orílẹ̀-èdè kí àwọn ọlọ̀tẹ̀ má ṣe gbé ara wọn ga. Sela.