Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Pharisees: Left Judea for a time on account of

3 ẹsẹ · 42 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Left Judea for a time on account of

  1. Àwọn Farisi sì gbọ́ pé, Jesu ni, ó sì ń ṣe ìtẹ̀bọmi fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn púpọ̀ ju Johanu lọ.

  2. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Jesu tìkára rẹ̀ kò ṣe ìtẹ̀bọmi bí kò ṣe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀,

  3. Ó fi Judea sílẹ̀, ó sì tún lọ sí Galili.