Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Pharisees: Imputed Christ's miracles to Satan's power

2 ẹsẹ · 42 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Imputed Christ's miracles to Satan's power

  1. Ṣùgbọ́n àwọn Farisi wí pé, “Agbára olórí àwọn ẹ̀mí èṣù ni ó fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.”

  2. Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn Farisi gbọ́ èyí, wọ́n wí pé, “Nípa Beelsebulu nìkan, tí í ṣe ọba ẹ̀mí èṣù ni ọkùnrin yìí fi lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.”