Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Moon: Signs in, before the destruction of Jerusalem
Àwọn ẹsẹ nípa Signs in, before the destruction of Jerusalem
“Àmì yóò sì wà ní oorun, àti ní òṣùpá, àti ní ìràwọ̀; àti lórí ilẹ̀ ayé ìdààmú fún àwọn orílẹ̀-èdè nínú ìpayà híhó Òkun àti ìgbì omi.