Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Moon: Lunacy attributed to the influence of

2 ẹsẹ · 29 abala

Wá "The Moon"

Àwọn ẹsẹ nípa Lunacy attributed to the influence of

  1. Oòrùn kì yóò pa ọ́ ní ìgbà ọ̀sán tàbí òṣùpá ní ìgbà òru.

  2. Òkìkí rẹ̀ sì kàn yí gbogbo Siria ká; wọ́n sì gbé àwọn aláìsàn tí ó ní onírúurú ààrùn, àwọn tí ó ní ìnira ẹ̀mí èṣù, àti àwọn ti o ní wárápá àti àwọn tí ó ní ẹ̀gbà; ó sì wò wọ́n sàn.