Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Synagogues: Preached and taught in
Àwọn ẹsẹ nípa Preached and taught in
Jesu sì rin káàkiri gbogbo Galili, ó ń kọ́ni ní Sinagọgu, ó ń wàásù ìyìnrere ti ìjọba ọ̀run, ó sì ń ṣe ìwòsàn ààrùn gbogbo àti àìsàn láàrín gbogbo ènìyàn.
Nítorí náà, ó ń kiri gbogbo agbègbè Galili, ó ń wàásù nínú Sinagọgu. Ó sì ń lé àwọn ẹ̀mí àìmọ́ jáde.
Ó sì ń kọ́ni nínú Sinagọgu kan ní ọjọ́ ìsinmi.