Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Synagogues: Praise and thanksgiving

1 ẹsẹ · 27 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Praise and thanksgiving

  1. Nígbà náà ni àwọn ọmọ Lefi: Jeṣua, Kadmieli, Bani, Haṣbneiah, Ṣerebiah, Hodiah, Ṣebaniah àti Petahiah—wí pé, “Ẹ dìde ẹ fi ìyìn fún Olúwa Ọlọ́run yín, tí ó wà láé àti láéláé.” “Ìbùkún ni fún orúkọ rẹ tí ó ní ògo, kí ó sì di gbígbéga ju gbogbo ìbùkún àti ìyìn lọ.