Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Synagogues: Provided with a minister, who had charge of the sacred books

2 ẹsẹ · 27 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Provided with a minister, who had charge of the sacred books

  1. A sì fi ìwé wòlíì Isaiah fún un. Nígbà tí ó sì ṣí ìwé náà, ó rí ibi tí a gbé kọ ọ́ pé:

  2. Ó sì pa ìwé náà dé, ó fi í fún ìránṣẹ́, ó sì jókòó. Gbogbo àwọn tí ó ń bẹ nínú Sinagọgu sì tẹjúmọ́ ọn.