Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shoes: Called sandals

2 ẹsẹ · 23 abala

Wá "Shoes"

Àwọn ẹsẹ nípa Called sandals

  1. Wọn kò tilẹ̀ gbọdọ̀ mú ìpààrọ̀ bàtà tàbí aṣọ lọ́wọ́.

  2. Angẹli náà sì wí fún un pé, “Di àmùrè rẹ̀, kí ó sì wọ sálúbàtà rẹ!” Peteru sì ṣe bẹ́ẹ̀. Ó sì wí fún un pé, “Da aṣọ rẹ́ bora, ki ó sì máa tọ̀ mí lẹ́yìn!”