Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ships: The hinder part of, occupied by the passengers
Àwọn ẹsẹ nípa The hinder part of, occupied by the passengers
Jesu ti sùn lọ lẹ́yìn ọkọ̀, ó gbé orí lé ìrọ̀rí. Wọ́n sì jí i lóhùn rara wí pé, “Olùkọ́ni, tàbí ìwọ kò tilẹ̀ bìkítà pé gbogbo wa fẹ́ rì?”