Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ships: Course of frequently directed by the heavenly bodies
Àwọn ẹsẹ nípa Course of frequently directed by the heavenly bodies
Nígbà tí oòrùn àti ìràwọ̀ kò si hàn lọ́jọ́ púpọ̀, tí ìjì náà kò sì mọ níwọ̀n fún wa, àbá àti là kò sí fún wa mọ́.