Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ships: Of Chaldea

1 ẹsẹ · 53 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Of Chaldea

  1. Èyí ni ohun tí Olúwa wí, olùràpadà rẹ, Ẹni Mímọ́ ti Israẹli: “Nítorí rẹ Èmi yóò ránṣẹ́ sí Babeli láti mú wọn sọ̀kalẹ̀ wá gẹ́gẹ́ bí ìsáǹsá, gbogbo ará Babeli, nínú ọkọ̀ ojú omi nínú èyí tí wọ́n fi ń ṣe ìgbéraga.