Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Selfishness: The love of Christ should constrain us to avoid

2 ẹsẹ · 28 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The love of Christ should constrain us to avoid

  1. Nítorí ìfẹ́ Kristi ń rọ̀ wá, nítorí àwa mọ̀ báyìí pé, bí ẹnìkan bá kú fún gbogbo ènìyàn, ǹjẹ́ nígbà náà, gbogbo wọ́n ni ó ti kú.

  2. Ó sì ti kú fún gbogbo wọn, pé kí àwọn tí ó wà láààyè má sì ṣe wà láààyè fún ara wọn mọ́, bí kò ṣe fún ẹni tí ó kú nítorí wọn, tí ó sì ti jíǹde.