Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Selfishness: Especially forbidden to saints
Àwọn ẹsẹ nípa Especially forbidden to saints
Má ṣe ronú nípa ara rẹ̀ nìkan; ṣùgbọ́n kí olúkúlùkù máa wá rere ọmọnìkejì rẹ̀.
Kí olúkúlùkù yín má ṣe ro ohun ti ara rẹ̀ nìkan, ṣùgbọ́n ti ẹlòmíràn pẹ̀lú.