Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sanitation: Childbirth
Àwọn ẹsẹ nípa Childbirth
Ní ọjọ́ kẹjọ ni kí ẹ kọ ọmọ náà ní ilà.
Ní ọjọ́ tí a bí ọ, a kò gé okùn ìwọ́ rẹ, bẹ́ẹ̀ ni a kò sì fi omi wẹ̀ ọ́ láti mú kí o mọ́, a kò fi iyọ̀ pa ọ́ lára rárá, bẹ́ẹ̀ ni a kò fi aṣọ wé ọ.