Mishael
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Mishael
Àwọn ọmọ Usieli ni: Miṣaeli, Elsafani àti Sitiri.
Mose pe Miṣaeli àti Elsafani ọmọ Usieli tí í ṣe arákùnrin Aaroni, ó sọ fún wọn pé, “Ẹ wá, kí ẹ sì gbé àwọn arákùnrin yín jáde kúrò níwájú ibi mímọ́ lọ sí ẹ̀yìn ibùdó.”