Elizaphan
A tún mọ̀ ọ́n sí: Elzaphan
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Elizaphan
Àwọn ọmọ Usieli ni: Miṣaeli, Elsafani àti Sitiri.
Mose pe Miṣaeli àti Elsafani ọmọ Usieli tí í ṣe arákùnrin Aaroni, ó sọ fún wọn pé, “Ẹ wá, kí ẹ sì gbé àwọn arákùnrin yín jáde kúrò níwájú ibi mímọ́ lọ sí ẹ̀yìn ibùdó.”
Olórí àwọn ìdílé Kohati ni Elisafani ọmọ Usieli.
Igba nínú àwọn ọmọ Elisafani; Ṣemaiah olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀.
nínú àwọn ọmọ Elisafani, Ṣimri àti Jeieli; nínú àwọn ọmọ Asafu, Sekariah àti Mattaniah;