Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salvation: Should endure suffering that the elect may obtain
Àwọn ẹsẹ nípa Should endure suffering that the elect may obtain
Nítorí náà mo ń faradà ohun gbogbo nítorí àwọn àyànfẹ́; kí àwọn náà pẹ̀lú lè ní ìgbàlà tí ń bẹ nínú Kristi Jesu pẹ̀lú ògo ayérayé.