Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salvation: Preaching the word is the appointed means of
Àwọn ẹsẹ nípa Preaching the word is the appointed means of
Nítorí pé, nínú ọgbọ́n Ọlọ́run, ayé kò le mọ̀ òun nípa ọgbọ́n àti ìṣeféfé wọn. Ó sì gba gbogbo àwọn tí ó gbàgbọ́ là nípa ìwàásù tí àwọn aráyé pè ní òmùgọ̀ àti ọ̀rọ̀ ọ yẹ̀yẹ́.