Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salvation: Should use self-denial to lead others to
Àwọn ẹsẹ nípa Should use self-denial to lead others to
Nígbà tí mo bá wà láàrín àwọn aláìlera, èmi náà yóò di aláìlera, kí èmi lé jèrè àwọn aláìlera. Mo di ohun gbogbo fún gbogbo ènìyàn, kí èmi ba à lè gba díẹ̀ là lábẹ́ bí ó ti wù kí ó rí.