Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salvation: Came to the Gentiles through the fall of the Jews
Àwọn ẹsẹ nípa Came to the Gentiles through the fall of the Jews
Ǹjẹ́ mo ní, wọ́n ha kọsẹ̀ kí wọn kí ó lè ṣubú? Kí a má ri i, ṣùgbọ́n nípa ìṣubú wọn, ìgbàlà dé ọ̀dọ̀ àwọn Kèfèrí, láti mú Israẹli jowú.